“Adédọ̀tun” by Brymo is a song that uses the names Adedotun and Oyindamola to represent the average man and woman, reflecting on the struggles and blessings of life and divine provision. The lyrics praise and celebrate these individuals, likening them to birds that are fed by God, while encouraging persistence and forward movement.
Verse 1
Awon adan fo loke
Wan foka si oju Orun
Wan o ma mo ibi won lo
Eledua lo n shey ike won
Ko keyin si é Oré o
O wun o n wa
O wa ni waju re
Hook
Adedotun.......
Oyindamola mi.......
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o.............
Verse 2
Awon adan fo loke
Ni igba igba
Won ku oju orun
Won o ma mo iwun wan n je
Eledua lo n sho wan
Lo n bo wan
Ko pamo si é
Oré ooooooo
O wa lo sokoto
O wa lapo Sokoto
Hook
Adedotun.......
Oyindamola mi.......
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o.............
(X2)
Ko pamo si é
Oré o
Owun o n wa
O wa ni waju re
Ore o........
Uploaded by: Enobong • Upload date: 11/21/2025
More Songs by Brymo
Talk and D...
2Baba (Tuface),...
Time
Brymo, Deborah ...
