“ODUMODUBLVCK,” titles his new track “RAMADAN KAREEM” which means “generous Ramadan.” He uses this greeting, used to wish someone a blessed and generous month during Ramadan, to create a song filled with thick imagery, describing the boisterous feast he will enjoy with his Muslim friends after the month ends. He features talented artistes, “Boj” and “Tolibian” in this track.
Saari, saari ti to Musulumi ẹ didé n'lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
B'ọn gb'ounjẹ wa, mi o ni le jẹun
B'ọn gb'omi wa, mi o ni le mu o
Agba to l'omi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[?]
Black sheep forever, black sheep for life
Izgaaju 'til we kpeme, Antiworld gangsters
GE records, you get me? ODUMODUBLVCK
Kala
Musa serve me my saari suya
If that na where my niggas dey gather
If you think I'm fapping it, you're right accordingly
[?]
When you been dey sisi, you dey jolly Ramadan Kareem (Opor)
[?]
L'ale Ramadan (Ehn)
[?]
L'ale Ramadan (Ehn)
Ibe la ti n ma ṣ'ere pa
L'ale Ramadan (Eyy)
Salam alaikum, wa alaikum assalam
E didé, e didé, e didé le
Saari, saari ti to Musulumi ẹ dide n'lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
B'ọn gb'ounjẹ wa mi o ni le jẹun
B'ọn gb'omi wa mi o ni le mu o
Agba to l'omi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[Non-Lyrcal vocals]
Ẹ ye fa baki lọsan Ramadan
Ẹ ye gb'oloṣo lọsan Ramadan
Ẹ ma ṣe ṣaṣe ninu Ramadan
O ṣi tun wẹ'ṣẹ ninu Ramadan
Yeah, yeah, yeah
Uploaded by: Itoro • Upload date: 11/5/2025
More Songs by ODUMODUBLVCK
Snakes
ODUMODUBLVCK, R...
Her Presen...
ODUMODUBLVCK, R...
Who? (Na M...
ODUMODUBLVCK, R...
Very Big B...
ODUMODUBLVCK, R...
Vanity
ODUMODUBLVCK, R...
Finesse
ODUMODUBLVCK, R...
Carry
ODUMODUBLVCK, R...
